Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 12:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí kò bá lágbára àti fi àgùntàn ṣe é, ó gbọdọ̀ le mú àdàbà méjì tàbí ọmọ ẹyẹlé méjì, ọ̀kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀, àti èkejì fún ẹbọ sísun. Báyìí ni àlùfáà yóò ṣe ètùtù fún un. Òun yóò sì di mímọ́.’ ”

Ka pipe ipin Léfítíkù 12

Wo Léfítíkù 12:8 ni o tọ