Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 12:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nígbà tí ọjọ́ ìwẹ̀nùmọ́ rẹ̀ fún ọmọkùnrin tàbí ọmọbìnrin bá kọjá kí ó mú ọ̀dọ́ àgùntàn ọlọ́dún kan wá fún àlùfáà ní ẹnu ọ̀nà àgọ́ ìpàdé fún ẹbọ sísun àti ọmọ ẹyẹlé tàbí àdàbà kan fún ẹbọ ẹ̀ṣẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 12

Wo Léfítíkù 12:6 ni o tọ