Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 12:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí ó bá ṣe obìnrin ni ó bí, fún ọ̀sẹ̀ méjì ni obìnrin náà yóò fi wà ní ipò àìmọ́, gẹ́gẹ́ bí àkókò nǹkan oṣù rẹ̀. Ó sì gbọdọ̀ dúró ní ọjọ́ mẹ́rìndínláàdọ́rin (66) láti di mímọ́ kúrò nínú ìsun ẹ̀jẹ̀ rẹ̀.

Ka pipe ipin Léfítíkù 12

Wo Léfítíkù 12:5 ni o tọ