Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 12:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Obìnrin náà yóò sì dúró fún ọjọ́ mẹ́talélọ́gbọ̀n (33) láti di mímọ́ kúrò nínú ìsun ẹ̀jẹ̀ rẹ̀. Kò gbọdọ̀ fi ọwọ́ kan ohunkóhun tí ó jẹ́ mímọ́ tàbí kí ó lọ sí ibi mímọ́ Olúwa títí di ọjọ́ tí ìwẹ̀nùmọ́ rẹ̀ yóò kọjá.

Ka pipe ipin Léfítíkù 12

Wo Léfítíkù 12:4 ni o tọ