Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 1:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó fi omi ṣàn nǹkan inú àti àwọn ẹsẹ̀ rẹ̀, kí àlùfáà sì sun gbogbo rẹ̀ lórí pẹpẹ, ó jẹ́ ọrẹ ẹbọ sísun, ọrẹ ẹbọ tí a fi iná ṣe, àní òórùn dídùn sí Olúwa.

Ka pipe ipin Léfítíkù 1

Wo Léfítíkù 1:9 ni o tọ