Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Léfítíkù 1:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà ni àwọn ọmọ Árónì tí í ṣe àlùfáà yóò tò ègé ẹran náà, pẹ̀lú orí àti ọ̀rá rẹ̀ sí ori igi tó ń jó lórí pẹpẹ.

Ka pipe ipin Léfítíkù 1

Wo Léfítíkù 1:8 ni o tọ