Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 8:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ yóò sì ṣe sí Áì àti ọba rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí ìwọ ti ṣe sí Jẹ́ríkò àti ọba rẹ̀, ohun ìkógun wọn àti ohun ọ̀sìn wọn ni kí ẹ̀yin mú fún ara yín. Rán ènìyàn kí wọ́n ba sí ẹ̀yìn ìlú náà.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 8

Wo Jóṣúà 8:2 ni o tọ