Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 7:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Lọ, ya àwọn ènìyàn náà sí mímọ́. Sọ fún wọn pé, ‘Ẹ ya ara yín sí mímọ́ fún ọ̀la, nítorí báyìí ni Olúwa, Ọlọ́run Ísírẹ́lì wí: Ohun ìyàsọ́tọ̀ kan ń bẹ ní àárin yín, Ìwọ Ísírẹ́lì. Ẹ̀yin kì yóò lè dúró níwájú àwọn ọ̀ta a yín títí ẹ̀yin yóò fi mú kúrò.

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:13 ni o tọ