Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 7:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìdí nì-yí tí àwọn ará Ísírẹ́lì kò fi lè dúró níwájú àwọn ọ̀ta wọn; wọ́n yí ẹ̀yín wọn padà, wọ́n sì sálọ níwájú ọ̀ta a wọn nítorí pé àwọn gan-an ti di ẹni ìparun. Èmi kì yóò wà pẹ̀lú u yín mọ́, bí kò se pé ẹ̀yin pa ohun ìyàṣọ́tọ̀ run kúrò ní àárin yín.

Ka pipe ipin Jóṣúà 7

Wo Jóṣúà 7:12 ni o tọ