Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 24:32 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Egungun Jóṣéfù, èyí tí àwọn ọmọ Ísírẹ́lì kó kúrò ní Éjíbítì, ni wọ́n sin ní Ṣékémù ní ìpín ilẹ̀ tí Jákọ́bù rà fún ọgọ́ọ̀rún (100) fàdákà ní ọwọ́ Hámórì, baba Ṣékémù. Èyí sì jẹ́ ilẹ̀-ìní àwọn ọmọ Jósẹ́fù.

Ka pipe ipin Jóṣúà 24

Wo Jóṣúà 24:32 ni o tọ