Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 24:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Lẹ́yìn náà ni ẹ ré kọjá Jọ́dánì, tí ẹ sì wá sí Jẹ́ríkò. Àwọn ará ìlú Jẹ́ríkò sì bá yín jà, gẹ́gẹ́ bí ará Ámórì, Pérísì, Kénánì, Hítì, Gígásì, Hífì àti Jébúsì. Ṣùgbọ́n mo fi wọ́n lé e yín lọ́wọ́.

Ka pipe ipin Jóṣúà 24

Wo Jóṣúà 24:11 ni o tọ