Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 22:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Àwa sì wí pé, ‘Tí wọ́n bá tilẹ̀ sọ èyí fún wa, tàbí sí àwọn ọmọ wa, a ó dáhùn pé: Ẹ wo àpẹrẹ pẹpẹ Olúwa, èyí tí àwọn baba wa mọ, kì í ṣe fún ọrẹ sísun àti ẹbọ ṣùgbọ́n fún ẹ̀rí láàrin àwa àti ẹ̀yin.’

Ka pipe ipin Jóṣúà 22

Wo Jóṣúà 22:28 ni o tọ