Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 22:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọ̀nà mìíràn, yóò jẹ́ ẹ̀rí kan láàárin àwa àti ẹ̀yin àti àwọn ìran tí ń bọ̀, pé àwa yóò jọ́sìn fún Olúwa ní ibi mímọ́ rẹ̀ pẹ̀lú ọrẹ sísun wa, ẹbọ àti ọrẹ àlàáfíà. Nígbà náà ni ẹ̀yìn ọ̀la, àwọn ọmọ yín kò ní lè sọ fún tiwa pé, ‘Ẹ kò ní ìpín nínú ti Olúwa.’

Ka pipe ipin Jóṣúà 22

Wo Jóṣúà 22:27 ni o tọ