Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 22:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kí Ọlọ́run má jẹ́ kí àwa kí ó ṣọ̀tẹ̀ sí Olúwa, kí àwa sì yípadà kúrò ní ọ̀dọ̀ rẹ ní òní nípa mímọ pẹpẹ fún ẹbọ sísun ọrẹ oúnjẹ jíjẹ àti ẹbọ lẹ́yìn pẹpẹ Olúwa Ọlọ́run wa tí ó dúró níwájú àgọ́ rẹ̀.”

Ka pipe ipin Jóṣúà 22

Wo Jóṣúà 22:29 ni o tọ