Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 20:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ìhà ìlà oòrùn Jọ́dánì ti Jẹ́ríkò, wọ́n ya Bésẹ́rìù ní aṣalẹ̀ ní pẹ̀tẹ́lẹ̀ ní ẹ̀yà Rúbẹ́nì, Rámótì ní Gílíádì ní ẹ̀yà Gádì, àti Golanì ní Básánì ní ẹ̀yà Mánásè.

Ka pipe ipin Jóṣúà 20

Wo Jóṣúà 20:8 ni o tọ