Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 20:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bẹ́ẹ̀ ni wọ́n yan Kedésì ní Gálílì ní ìlú òkè Náfítanì, Sékémù ní ìlú òkè Éfúráímù, àti Kíríátì aginjù (tí í ṣe, Hébúrónì) ní ìlú òkè Júdà.

Ka pipe ipin Jóṣúà 20

Wo Jóṣúà 20:7 ni o tọ