Wọ̀nyí ni àwọn ilẹ̀ tí Élíásárì àlùfáà, Jósúà ọmọ Núnì àti àwọn olórí ẹ̀yà agbo ilé Ísírẹ́lì fi ìbò pín ní Sílò ní iwájú Olúwa ní ẹnu-ọ̀nà Àgọ́ Ìpàdé. Báyìí ni wọ́n parí pínpín ilẹ̀ náà.