Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 19:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí Olúwa ti pàṣẹ, wọ́n fún-ún ni ìlú tí ó béèrè fún—Tímínátì Sérà ní ìlú òkè Éfúráímù. Ó sì kọ́ ìlú náà, ó sì ń gbé ibẹ̀.

Ka pipe ipin Jóṣúà 19

Wo Jóṣúà 19:50 ni o tọ