Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Síhónì ọba àwọn Ámorì,tí ó jọba ní Hésíbónì. Ó ṣe àkóso láti Ároérì tí ń bẹ ní etí Anoni-Gọ́gì, láti àárin Jọ́ọ́jì dé Odò Jábókì, èyí tí ó jẹ́ ààlà àwọn ọmọ Ámónì. Pẹ̀lú ìdajì àwọn ará Gílíádì.

Ka pipe ipin Jóṣúà 12

Wo Jóṣúà 12:2 ni o tọ