Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 12:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ̀nyí ní àwọn ọba ilẹ̀ náà tí àwọn ará Ísírẹ́lì ṣẹ́gun, tí wọ́n sì gba ilẹ̀ wọn ní ìlà-oòrùn Jọ́dánì, láti Ánónì-Gọ́gi dé Okè Hámónì, pẹ̀lú gbogbo ìhà ìlà-oòrùn aginjù:

Ka pipe ipin Jóṣúà 12

Wo Jóṣúà 12:1 ni o tọ