Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 11:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Wọ́n sì fi idà pa gbogbo àwọn ènìyàn tí ó wà ní ibẹ̀. Wọ́n sì pa wọ́n run pátapáta, wọn kò sì fi ohun alàyè kan sílẹ̀; ó sì fi iná sun Hásóri fúnrarẹ̀.

Ka pipe ipin Jóṣúà 11

Wo Jóṣúà 11:11 ni o tọ