Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóṣúà 11:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní àkókò náà Jóṣúà sì padà sẹ́yìn, ó sì ṣẹ́gun Hásórù, ó sì fi idà pa ọba rẹ̀. (Hásóri tí jẹ́ olú fún gbogbo àwọn ìlú wọ̀nyí Kó tó di àkókò yí.)

Ka pipe ipin Jóṣúà 11

Wo Jóṣúà 11:10 ni o tọ