Olúwa sì bi Sàtanì wí pé, “Níbo ni ìwọ ti wá?”Nígbà náà ní Sàtanì dá Olúwa lóhùn wí pé, “Ní ìlọ-siwá-sẹ́yìn lórí ilẹ ayé, àti ní ìrìnkèrindò nínú rẹ̀.”