Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 2:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Iná ń jó níwájú wọ́n;ọwọ́ iná sì ń jó lẹ́yìn wọn:ilẹ̀ náà dàbí ọgbà Édẹ́nì níwájú wọn,àti lẹ́yìn wọn bí ahoro ijù;nítòótọ́, kò sì sí ohun tí yóò bọ́ lọ́wọ́ wọn.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 2

Wo Jóẹ́lì 2:3 ni o tọ