Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 2:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọjọ́ òkùnkùn àti òkùdù,ọjọ́ ìkùùkù àti òkùnkùn biribiri,bí ọyẹ́ òwúrọ̀ ti í la bo orí àwọn òkè ńlá:àwọn ènìyàn ńlá àti alágbára; ya dé,ti kó ti ì sí irú rẹ̀ rí,bẹ́ẹ̀ ni irú rẹ̀ kì yóò sí mọ́ lẹ́yìn rẹ̀, títí dé ọdún ìran dé ìran.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 2

Wo Jóẹ́lì 2:2 ni o tọ