“Yóò sì ṣe,èmi yóò tú ẹ̀mi mí sí ara ènìyàn gbogbo;àti àwọn ọmọ yín ọkùnrin,àti àwọn ọmọ yín obìnrin yóò máa ṣọtẹ́lẹ̀,àwọn arúgbó yín yóò máa lá àlá,àwọn ọ̀dọ́mọ́kunrìn yín yóò máa ríran.