Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 2:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin yóò sì mọ̀ pé, èmi wà láàrin Ísírẹ́lì,àti pé; Èmi ni Olúwa Ọlọ́run yín,ati pé kò sí ẹlòmíràn:ojú kì yóò sì ti àwọn ènìyàn mí láéláé.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 2

Wo Jóẹ́lì 2:27 ni o tọ