Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 2:17 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jẹ́ kí àwọn àlùfáà, àwọn ìránṣẹ́ Olúwa,sọkún láàrin ìlorò àti pẹpẹ,sí jẹ́ kí wọn wí pé, “Dá àwọnènìyàn rẹ sí Olúwa,má sì ṣe fi ìní rẹ fun ẹ̀gàn,ti àwọn aláìkọlà yóò fi má jọba lórí wọn:èéṣe tí wọn yóò fi wí láàárin àwọn ènìyàn pé,‘Ọlọ́run wọn há da?’ ”

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 2

Wo Jóẹ́lì 2:17 ni o tọ