Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 2:16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ kó àwọn ènìyàn jọ,ẹ ya ìjọ sí mímọ́;ẹ pe àwọn àgbà jọ,ẹ kó àwọn ọmọdé jọ,àti àwọn tí mú ọmú:jẹ kí ọkọ ìyàwó kúrò nínú iyẹ̀wù rẹ̀.Kí ìyàwó sì kúrò nínù ìyàrá rẹ̀

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 2

Wo Jóẹ́lì 2:16 ni o tọ