Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 2:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa yóò sì bú rámu ramùjáde níwájú ogun rẹ̀:nítorí ibùdó rẹ̀ tóbi gidigidi;nítorí alágbára ní òun, tí n mú ọ̀rọ rẹ̀ ṣẹ;nítorí ọjọ́ Olúwa tóbi ó sì ní ẹ̀rù gidigidi;ara ta ni ó lè gbà á?

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 2

Wo Jóẹ́lì 2:11 ni o tọ