Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 1:6-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

6. Nítorí orílẹ̀ èdè kan ti sígun sí ilẹ̀ mìírànó ní agbára púpọ̀, kò sì ní òǹkà;ó ní eyín kìnnìúnó sì ní èrìgì abo kìnnìún.

7. Ó ti pa àjàrà mi run,ó sì ti ya ẹ̀ka igi ọ̀pọ̀tọ́ mi kúrò,ó ti bò èèpo rẹ̀ jálẹ̀, ó sì sọ ọ́ nù;àwọn ẹ̀ka rẹ̀ ni a sì sọ di fun-fun.

8. Ẹ pohùnréré ẹkún bí wúndíátí a fi aṣọ ọ̀fọ̀ dí ni àmúre, nítorí ọkọ ìgbà èwe rẹ̀.

9. A ké ọrẹ jíjẹ́ àti ọrẹ mímú kúròní ilé Olúwa;àwọn àlùfáà ń ṣọ̀fọ̀, àwọnìrànṣẹ́ Olúwa,

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 1