Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 1:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ jí gbogbo ẹ̀yín ọ̀mùtí kí ẹ sì ṣunkúnẹ pohùnréré ẹkún gbogbo ẹ̀yinọ̀mu-wáìnì; ẹ pohùnréré ẹkún nítorí wáìnì tuntunnítorí a gbà á kúrò lẹ́nu yín.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 1

Wo Jóẹ́lì 1:5 ni o tọ