Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 1:18-20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

18. Àwọn ẹranko tí ń kerora tó!Àwọn agbo ẹran dààmú,nítorí tí wọ́n kò ni pápá oko;nítòótọ́, àwọn agbo àgùntàn jìyà.

19. Olúwa, sí ọ ni èmi o ké pè,nítorí iná tí run pápa oko tútú ihà,ọwọ́ iná sí ti jó gbogbo igi igbó.

20. Àwọn ẹranko igbó gbé ojú sókè sí ọ pẹ̀lú:nítorí tí àwọn iṣàn omi gbẹ,iná sí ti jó àwọn pápá oko ihà run.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 1