Àwọn ẹranko tí ń kerora tó!Àwọn agbo ẹran dààmú,nítorí tí wọ́n kò ni pápá oko;nítòótọ́, àwọn agbo àgùntàn jìyà.