Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 1:13 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ di ara yín ni àmùrè,sí pohùn réré ẹkún ẹyín àlùfáà:ẹ pohùn réré ẹkún, ẹyín ìránṣẹ́ pẹpẹ:ẹ wá, fi gbogbo òru dùbúlẹ̀ nínú aṣọ ọ̀fọ̀,ẹ̀yin ìrànsẹ́ Ọlọ́run mi: nítorí tí a dá ọrẹ jíjẹ àti ọrẹmímú dúró ní ilé Ọlọ́run un yín.

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 1

Wo Jóẹ́lì 1:13 ni o tọ