Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jóẹ́lì 1:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àjàrà gbẹ, igi ọ̀pọ̀tọ́ sì rọ̀ dànù;igi pómégánátì, igi ọ̀pẹ pẹ̀lú,àti igi ápíílì, gbogbo igi igbó ni o rọ:Nítorí náà ayọ̀ ọmọ ènìyàn gbẹ kúrò lọ́dọ̀ wọn

Ka pipe ipin Jóẹ́lì 1

Wo Jóẹ́lì 1:12 ni o tọ