Èyí ni ohun tí Olúwa Àwọn ọmọ ogun wí:“Jẹ́ kí wọn pesẹ́ ìyókù Ísírẹ́lìní tónítóní bí àjàrà;na ọwọ́ rẹ sí àwọn ẹ̀ka nì lẹ́ẹ̀kan sí igẹ́gẹ́ bí ẹnìkan ti í kó èṣo àjàrà jọ.”