Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 6:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ta ni ẹni tí mo lè bá sọ̀rọ̀ àtití mo lè fún ní ìmọ̀ràn? Ta niyóò tẹ́tí sílẹ̀ sí mi? Etí wọnti di, nítorí náà wọn kò lè gbọ́.Ọ̀rọ̀ Olúwa, jẹ́ ohun búburú sí wọn,wọn kò sì ní inú dídùn nínú rẹ̀.

Ka pipe ipin Jeremáyà 6

Wo Jeremáyà 6:10 ni o tọ