Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 51:62 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ìwọ kí ó sì wí pé, ‘Olúwa ìwọ ti sọ̀rọ̀ sí ibí yí, láti ké e kúrò, kí ẹnikẹ́ni má ṣe gbé inú rẹ̀, àti ènìyàn àti ẹran, nítorí pé yóò di ahoro láéláé.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 51

Wo Jeremáyà 51:62 ni o tọ