Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 51:50 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ẹ̀yin tí ó ti bọ́ lọ́wọ́ idà, ẹ lọ, ẹ má dúró:Ẹ rántí Olúwa ní òkèrè,ẹ sì jẹ́ kí Jérúsálẹ́mù wá sí ọkàn yín.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 51

Wo Jeremáyà 51:50 ni o tọ