Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 47:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n bá gbọ́ ìró títẹlẹ̀ pátakò ẹsẹ̀ ẹṣin alágbáranígbà tí wọ́n bá gbọ́ ariwo kẹ̀kẹ́ ogun ọ̀tá ńláàti iye kẹ̀kẹ́ wọn.Àwọn baba kò ní lè ran àwọn ọmọ lọ́wọ́;ọwọ́ wọn yóò kákò.

Ka pipe ipin Jeremáyà 47

Wo Jeremáyà 47:3 ni o tọ