Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 47:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni Olúwa wí:“Wo bí omi ti ń ru sókè ní àríwá,wọn ó di odò tí ń bo bèbè mọ́lẹ̀.Wọn ò ní borí ilẹ̀ àti ohun gbogbo tó wà lórí rẹ̀,ìlú àti àwọn tó ń gbé nínú wọn.Àwọn ènìyàn yóò kígbe;gbogbo ẹni tó ń gbé lórí ilẹ̀ yóò pohùnréré ẹkún

Ka pipe ipin Jeremáyà 47

Wo Jeremáyà 47:2 ni o tọ