Nítorí tí ọjọ́ náà ti péláti pa àwọn Fílístínì run,kí a sì mú àwọn tí ó làtí ó lè ran Tírè àti Sídónì lọ́wọ́ kúrò. Olúwa ti ṣetán láti pa Fílístínì run,àwọn tí ó kù ní agbègbè Káfútò.