Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 46:28 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Má bẹ̀rù, Jákọ́bù ìránṣẹ́ mi,nítorí pé mo wà pẹ̀lú rẹ,” bẹ́ẹ̀ ni Olúwa wí.“Bí mo tilẹ̀ pa gbogbo orílẹ̀ èdè run,láàrin àwọn tí mo fọ́n yín ká sí.Èmi kò ní run yín tán.Èmi yóò jẹ ọ́ níyà lórí òdodo,èmi kò ní fi ọ́ sílẹ̀ láìjẹ ọ́ níyà.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 46

Wo Jeremáyà 46:28 ni o tọ