Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 46:27 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Má bẹ̀rù, ìwọ Jákọ́bù ìránṣẹ́ mi,má fòyà, ìwọ Ísírẹ́lì.Dájúdájú èmi ó gbà ọ́ láti ọ̀nà jínjìn,àwọn ọmọ ọmọ rẹ ní ilẹ̀ ìgbèkùn.Jákọ́bù yóò tún ní àlàáfíà àti ààbò,kò sì sí ẹni tí yóò dẹ́rù bà á.

Ka pipe ipin Jeremáyà 46

Wo Jeremáyà 46:27 ni o tọ