Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 4:31 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo gbọ́ ìró kan bí i igbe obìnrin tó ń rọbí,tí ó ń rọbí, ìrora bí i abiyamọọmọbìnrin Síónì tí ń pohùnréré ẹkún ara rẹ̀.Tí ó na ọwọ́ rẹ̀ tí ó sì wí pé,“Kíyèsí i mo gbé,Nítorí a ti fi ẹ̀mí mi lé àwọn apani lọ́wọ́.”

Ka pipe ipin Jeremáyà 4

Wo Jeremáyà 4:31 ni o tọ