Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 4:30 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ni ò ń ṣe, ìwọ tí o ti di ìjẹ tán?Ìwọ ìbá wọ ara rẹ ní aṣọ òdodokí o sì fi wúrà ṣe ara rẹ lọ́ṣọ̀ọ́.Àwọn olólùfẹ́ rẹ kẹ́gàn rẹwọ́n sì ń lépa ẹ̀mí rẹ.

Ka pipe ipin Jeremáyà 4

Wo Jeremáyà 4:30 ni o tọ