Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 38:20-22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

20. Jeremáyà sì dáhùn wí pé, “Wọn kò ní fi ọ́ lé e lọ́wọ́. Pa ọ̀rọ̀ Olúwa mọ́ nípa ṣíṣe ohun tí mo sọ fún ọ; yóò sì dára fún ọ, ẹ̀mí rẹ yóò sì wà.

21. Ṣùgbọ́n bí ìwọ bá kọ̀ láti jọ̀wọ́ ara rẹ, èyí ni ohun tí Olúwa ti fi hàn mí:

22. Gbogbo àwọn obìnrin tó kù ní ààfin Ọba Júdà ni wọn yóò kó jáde fún àwọn ìjòyè Ọba Bábílónì. Àwọn obìnrin náà yóò sì sọ fún ọ pé:“ ‘Àwọn ọ̀rẹ́ rẹ tàn ọ́ jẹ,wọ́n sì borí rẹ.Ẹsẹ̀ rẹ rì sínú orọ̀fọ̀;àwọn ọ̀rẹ́ rẹ ti fi ọ́ sílẹ̀.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 38