Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 38:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Jeremáyà sì dáhùn wí pé, “Wọn kò ní fi ọ́ lé e lọ́wọ́. Pa ọ̀rọ̀ Olúwa mọ́ nípa ṣíṣe ohun tí mo sọ fún ọ; yóò sì dára fún ọ, ẹ̀mí rẹ yóò sì wà.

Ka pipe ipin Jeremáyà 38

Wo Jeremáyà 38:20 ni o tọ