Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Jeremáyà 38:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbogbo àwọn obìnrin tó kù ní ààfin Ọba Júdà ni wọn yóò kó jáde fún àwọn ìjòyè Ọba Bábílónì. Àwọn obìnrin náà yóò sì sọ fún ọ pé:“ ‘Àwọn ọ̀rẹ́ rẹ tàn ọ́ jẹ,wọ́n sì borí rẹ.Ẹsẹ̀ rẹ rì sínú orọ̀fọ̀;àwọn ọ̀rẹ́ rẹ ti fi ọ́ sílẹ̀.’

Ka pipe ipin Jeremáyà 38

Wo Jeremáyà 38:22 ni o tọ